Maranatha Global

The Spirit and the bride say, “Come!” – Rev. 22:17

6
Aug

nigeria1Nje Aluyo Nipa Ti Ara Je Ami Wipe,  Olorun Fi Owo Si Yiyan ?

Filippi 4:12 – “Mo mo bi aa ti ise dir ire sile, mo mo bi aa ti ise di pupo, li ohunkohun ati li ohun gbogbo mo ti ko asiri ati maa je ajeyo ati lati wa li aije, lati maa ni aniju ati lati se alaini.”

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
6
Aug

nigeria1Ileri Olorun Fun Dafidi

I Kronika 17:1-4 “O si se, bi Dafidi ti joko ninu ile re, ni Dafidi so fun Natani woli pe, emi n gbe inu ile Kedari, sugbon apoti eri majemu Oluwa ngbe abe aso tita. Nigba naa ni Natani wi fun Dafidi pe, se ohun gbogbo ti m be ninu re, nitori ti Olorun wa pelu re, o si se ni oru kan naa ni oro Olorun to Natani wa wipe, lo, si so fun Dafidi iranse mipe, bayi li Oluwa wi, iwo ko gbodo ko ile fun mi lati ma gbe”

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
6
Aug

nigeria1“La Mi Li Oju, Ki Emi Le Ma Wo Ohun Iyanu Wonni Lati Inu Ofin Re”

Orin Dafidi 119:17-19

“Fi opolopo ba iranse re se,ki emi ki o le wa laaye, ki emi kio le pa oro re mo. Lami li oju, ki emi ki o le ma wo ohun iyanu wonni lati inu ofin re. Alejo li mi li aye, maase pa ase re mo fun mi.”

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
6
Jul

nigeria1Orin-Dafidi 119:1-8

Ibukun ni fun awon eniti o pe li ona naa, ti nrin ninu ofin Oluwa.  Ibukun ni fun awon tin pa eri re mo, ti si nwaa kiri tinu-tinu.  Nwon ko dese pelu, nwon nrin li ona re.  Iwo ti pase fun wa lati pa eko re mo gidigidi, ona mi iba je la sile lati ma pa ilana re mo.  Nigba naa li oju ki yio ti mi, nigbati emi ban juba ase re gbogbo, Emi o ma fi aya diduro sinsin yin o, Nigbati emi ba ti ko idajo ododo re, emi o pa liana re mo, mase ko mi sile patapata.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
5
Jun

nigeria1OJUSE LATI LODI SI ORO EKE

Lefitiku 5:1.  .  “Bi enikan ba si se, ti o si gbo ohun ibura, ti o si se eleri, bi oun ba ri tabi bi oun ba mo ti ko ba wi, eje ki o ru aisedede re”

Bibeli ko w ape ani ojuse lati se ati lati se awon ohun ti otoo.  Ninu opolopo igbese wa, eleyi ti o je wipe, awon ohun ti a ro pe, a ko se le je ese to buru pupo.  “ Nitori naa enit ti o ba mo rere ise ti ko si se, ese ni fun-un” (Jakobu 4:17) opolopo ilana ofin kakiri orilede agbaye, niwon ko bojuwo esun aileso ohun ti otoo.  Olorun nreti awon ohun kan lati odo wa pe, ki a ma se ati wipe ki a ma se awon nkan aigboran.  Ese iwe ti a ka ninu iwe lefitiku yi, fun wa ni apeere eyo kan.  O fun wa ni eko ti ose Pataki, eleyi ti o le ran awon ijo abele lowo lati ni okun ife ti o danmoran ati ifowosowopo ti o tobi lati le jo sise papo gege bi iko.  Olorun fe ki a se atunse lori gbogbo oro eke, eleyi ti a se lodo si eniyan miran nigbati a gbo won.  Eleyi ko so fun wa wipe, ki a so ara wa di wolewode tabi ki a ma se ayojuran si ibi ise tabi okowo elomiran.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
16
May

nigeria11Korinti 13:6 “Ki iyo si aisododo, sugbon a maa yo ninu otito”.

Ife Amaa yo Ninu Otito

Eleyi le je ohun ti o faa, ti a ko fi menu ba awon oro kookan ninu iwe 1korinti 13.  Nigbati awon eniyan mba nro nipa oju ewe ife ti o tobi ju ninu iwe paulu.  Nigbogbo igba ni nwon maa nro wipe, boya nipa oyaya, tabi ki iwa eniyan dara, ati bi iru awon ohun ti amu enu baa ninu iwe 1korinti 13-4-5.  Oje ohun ti o sowon ka to le gbo iwaasu lori “ife” ni ona ti o je wipe, amaa yo ninu otito, tabi, ki iyo si aisododo.  Bakanaa, Ese yi fi ipa gbogi iyipada han ninu eko lori ife.  Ninu gbogbo eso ife ti a ka sile, (Eso kesan wa ninu iwe 1korinti 13-4-5), Eleyi ti oni ise pelu ibasepo wa ati bi aun nse se pelu awon eniyan wa ninu ile ijosin.  Nibiyi, aun ri  eso iwa olukuluku, eleyi to nfi itara ife atokan wa onikuluku han, eleyi ti ki ise wipe ki won kan saa ti mon wipe ani ibasepo pelu awon eniyan eleyi ti o yi wa ka.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
14
May

hausa-mapKaunata murna da gaskiya, 1 Korantiyawa 13:6

1 Korantiyawa 13:6, “ƙauna ba ta farin ciki da mugunta, amma yana murna da gaskiya.” – niv,

“rejoiceth a cikin zunubinsa, amma rejoiceth da gaskiya, wato” – kjv

Wannan ko mai shaida a lokacin 1 Korantiyawa 13. Da zata babban “Ka ƙaunaci surar” a hannun Bulus wasiƙa, su kan yi zato, mai kyau, mai daɗi halayyan tsabi’o'in>Shuffim da 1 Korantiyawa 13:4 da 5. Yana da nadira ya ji huduban da shawarwarin da “Ƙauna, ” wato ma’anar da farin ciki da gaskiya ko recoiling saɓo daga.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Hausa | Blog
10
May

nigeria1IFE KI NI AKOSILE ASISE

IKorinti 13:5 “Ki ihuwa aito ki iwa ohun ara re, aki imu un binu beeni ki igbiro ohun buburu.” Idi niyi ti bibelim (KJV).

Ninu oro ti paulu so yii, tumo si pe lati ma ro oun buburu, tabi lati ma ko awon akosile asise ati iwa buburu. “Idi niyi ti bibeli (KJV) tun fi se alaye ju awon eya bibeli titun ayeode oni lo. Bakanna, eniyan to un gbe ninu ife, ko nilo lati ma ko asise ti omonikeji ba se si ninu ijo, ka si ma ma fi gbogbo igba foju si awon ohun buburu ti a se si wa, eleyi to le ma mu wa, wa ona lati gbesan. Ninu awon ise ife ati iwa ife, toun nfi ihuwa si wa han si elomiran.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
9
May

hausa-mapTun da farko a 1 Korantiyawa, sai Bulus ya ce ‘yan Ikilisiya ya raba wa phony auna takan ba a doye, 1 Korantiyawa 13:5

“dauna. .  . Yakan ba a doye.”, 1 Korantiyawa 13:5, niv,

“doth ya kintsu kanta asharkwatotonta, seeketh ta, ba ta jin tsokana, thinketh wani mugun mafarkansu, kjv,

Yunanancin lokacin da Bulus ya ba da aiki a nan ya nufi da zata mugunta ko yi Allah dukan lissafin miyagun cuta ko kuwa ya zalunci.” Saboda haka, Yakan fassara kjv shi kadan differently fiye da mafi versions zamani. Uwar matani kewayewa da musayar miyau da manufar maganarmu ke zaune a sauran mutum aibon. Mutum mai daunata ba zai cika gama Ubangiji ya rubuta wani dan Ikilisiya, wrongdoings, kuma ba za su tuna da mugayen cikin tunani, yadda za su sami fansa ko kuwa yaya za su yi laccan, dan’uwanka.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Hausa | Blog
14
Apr

nigeria1Bibi Olorun Lere Nipa bi ase le Gboran Si Ife Re

Onidajo 1:1-2.  “O si se lehin iku josua, ni awon omo Israeli bere lodo Oluwa wipe, tani yio tete goke to awon ara kenaani lo fun wa, lati ba won ja?  Oluwa si wipe, juda ni yio goke lo.  Kiyesi emi fi ile  na lee lowo.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog