Okan ninu igbekale ti Olorun pea won ijo wa si ni lati ma se irapada ninu agbara to wa ninu eje Kristi. Nipase eje Jesu ni a ri igbala, idarijin,
Eleyi ki se ohun tuntun ti asese se awari re. O je igbekale igbani. Awon oju ewe to wa ninu bibeli o kun fun orisirisi itan ati awon eko lori fifi eje se irubo eyi ti o mu ki a fi Jesu se irubo lori agbelebu. Eleyi mu ki o ta eje re sile fun wa. Opolopo awon ijo ode oni ni won ti gbagbe eleyi. A fi Jesu han fun araye nipase ati gegebi odo aguntan lati odo Olorun wa. Eni ti o ko ese araye lo (Johannu 1:29). Awon aposteli ko awon onigbagbo igba ni pe, laisi itaje sile ko si imukuro ese. (fun apeere, Heberu 9:22). O ko wa wipe Jesu mu awon nkan wonyii se nipa fifi ara re rubo lori igi agbelebu. Olorun pa ni dandan fun wa lati ma lo eleyi ninu gbogbo igbagbo wa, ni olori jori ati laarin ipejopo. Eyi je iwasu apapo fun gbogbo ile ijosin Maranatha lagbaye.