Maranatha Global

The Spirit and the bride say, “Come!” – Rev. 22:17

3
Apr

nigeria1Mordekai Gege bi Apere Emimimo

Esteri 10:3.  “ Nitori mordekai ara juda li o se ibikeji Ahaswerusi oba, osi tobi ninu awon ju, o si se itewogba lodo opolopo ninu awon arakunrin re, o nwa ire awon eniyan re, osi nsoro alaafia fun gbogbo awon iru omo re…”

Eleyi ni ese bibeli to gbehin ninu iwe esteri, eleyi to si fa akoko to se pataki jade ninu iwe naa pelu ise ati iwa  Mordekai, Mordekai je oludamonran fun esteri, eleyi to duro gege bi ise ati itoni emimimo, gege bi Mordekai se gbe esteri lori soke, emimimo ntoju awon ijo olododo, osi tun ntoju won nipase idari, ati ise won.  Awon omo ju igbanni ko wipe, Mordekai ni ede Heberu tumosi “Ororo titun”, iru eyiti aun lo ninu ororo mimo (wo Esksodu 30:22-31, eyiti oduro gege bi ifi ororo yan ti emimimo).  Esteri 10:3.  So awon koko marun to se pataki nipa Mordekai.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
3
Apr

nigeria1Kinin Aun pe ni Purimu

Esteri: 9:24-25. “Pe, Hamani omo medata, ara agagi ni ota gbogbo awon ju ti gbiro lati pa awon ju run, osi ti da puri, eyini ni ibo, lati pa won, ati lati run won, sugbon nigbati esteri to oba wa, o fi iwe pase pe, ki ete buburu ti ati pa si awon ju ki ole pada si ori oun tikalare, ati ki a so ati oun ati awon omo re ro sori igi. (Nitorinaa ni nwon se npe ojo wonni ni purinu bi oruko puri)”.
continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
27
Feb

nigeria1

Esteri 8:11 –  “ Ninu eyiti Oba fi ase fun gbogbo awon ju, ti o wa ni ilu gbogbo, lati ko ara won jo, ati duro gba emi ara won la, lati parun, lati pa, ati lati mu ki gbogbo agbara awon eniyan, ati igberiko naa, ti o ba fe kolu won, pelu awon omo wewe ati awon obinrin ki o segbe, kin won ki o si ko ini won fun ara won

Ara awon ohun to wuni lori ninu  ninu iwe Esteri ni wipe, nigbati Oba se akiyesi idite lati pa awon eniyan ju run.  (Gege bi Hamani se npete lati pa awon eniyan Olorun run patapata.  Bakanna, ko si ona Kankan ti won le fi pagidina lasigbo yi ju ki Mordekai ati Esteri ro Oba lati fi ase fun awon eniyan Olorun lori awon ota won.  Eleyi fi ara pe awon ofin Persiani igbaani.  Eleyi ti won ma nyi ase pada, nipa sise a tunse, tabi ki won fagi le, Dipo eyi ti won o fi so di ewo fun enikeni lati gbogun ti awon omo ju, ofin titun fi ase fun gbogbo awon ju lati ko ara won jo, ati lati gba emi ara won la, lati parun, lati pa, ati lati mu ki gbogbo agbara awon eniyan ati  ti igberiko naa, ti o ba fe kolu won.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
6
Feb

nigeria1Esteri 8:8 “Enyin kowe ewe li oruko oba, nitori awon ju bi enyin ti fe, ki e si fi oruko oba ko, ti a ba si fi oruka oba se edidi, enikan ko le yi pada”.

Awon ijoba Persiani aye igbani, won ni awon asa ti ko ba ofin ijoba won mu.  Awon ofin ti awon alase ijoba gbekele ni o je wipe ko se yipada.  Eleyi ti o da opolopo wahala ati isoro sile ni gbogbo igba ti oba ba ti fe yi ase to ti pa lase pada.  Ko ni le tu edidi naa wo.  (wo Danieli 6:11-15, ninu itan miran, ti iru isoro bayi tun ti dide).  Ninu iwe Esteri, ona kan gbogi ti oba fi le yipada, ni ki oba fun igbakeji re lase lati yipada.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
6
Feb

nigeria1Esteri 7:9-10 “Harbona okan ninu awon iwefa si wi niwaju oba pe, sa woo, igi ti o ga ni aadota igbowo ti Hamani ti ri nitori Mordekai ti o ti so oro rere fun oba, o wa li oro ni ile Hamani oba si wipe eso oro lori re.  Beeni nwon so Hamani ro sori igi ti o ti ri fun Mordekai, ibinu oba si ro.  ”

Hamani eyiti nse ota awon eniyan Olorun ti pari eto gbogbo lati se iku pa Mordekai sori igi ti o ti ri fun ni agbaala ile re.  Oro riri “igi fun ni” je ohun ti a le pe ni opo tabi agbelebu, eleyi ti a un nso awon elese ro si.  Ni ona airotele ninu lasigbo naa, Hamani tikalarare ku si ori igi ti o ti ri fun awon eniyan Olorun lati pa won run.  Ohun akori kan ti o farahan ninu gbogbo iwe Esteri ni a ti ri awon ohun meji ti o farahan, ikini ni wipe, awon ohun ti aun foju ri ninu aye, ati awon ohun ti emi, ti akole fi oju lasan ri.  Eyi lofa ti awon opolopo nkan ninu iwe Esteri fi nfarahan lehin meji (Ase Apeje Ahaswerusi lehin meji, ati bi ba Esteri jeun po lehin meji, ati lodo Mordekai, ati bebe lo.  Idi niyen ti iwe naa ko fi so nipa Olorun fun rare, Botile je wipe Olorun nse opolopo ise, ti o si ngbo opolopo adura patapata ninu itan naa.  Awon eniyan ti won fina si Olorun, ki ni oye ohun pato ti oun nsele ni arin won.  Bakanna, won ko ni oye pe, Olorun nsise larin awon.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
5
Feb

Kisii, KENYA

Kisii, KENYA

ESTHER 8:8

Gaki inwe rika rirube ase abayahudi, moribeke erieta riane inche omoruoti, morike buna morarore moribeke ekemanyererio ki’ebonyi yane, ekiagera rirube rinde rionsi ririkire na kobekwa erieta riomoruoti amo nekemanyererio keibonyi yaye onde tari orarioonchore.

Naki ogwancherwa oko kwabene nigo gokororekana koba okogeni ase abange baito, Korende Esteri nigo agokwana gochia ime mono ase enchera yokomanya okonene gwa kemoika okwo korengete ogotoreka gwaito, na kore amo noboronge bw’aNyasae, na boichire nobonge bw’amaabera aye.  Naki oboronge bw’amachiko a’Nyasae nigo bore obwa kare nakare obwo boatri goonchoka, korende nabatebirie ekeene, goika igoro na ense mbiete, korende ring’ana ria’Nyasae tirigoeta nonya nekemoa kienuguta eyemo tegegoeta bosa, korende goika bionsi biikerane.

Mathayo 5:18 naboigo Zaburi 119:160.  Naki oboronge bw’amachiko nobogima bwa kare na kare naboigo na oboronge bwaye, noboikeranu ase ere omonyene, naboigo takonyara goonchoka ekiatorierete omwando oye, gose takora goikerania oboronge bwaye.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , ,
Category : Ekegusii (Kisii) | Blog
30
Jan

Kisii, KENYA

Kisii, KENYA

ENDAMWAMU Y’OMOGAMBI EKAIRANA INSE

Esteri 7:9-10 Haribona oyomo bw’abasomba  abaare gokorera omoruoti akabora rora” orobambo  rore rwobotambe bwamaboko  emerongo etano , roria Hamani asimiseretie moredekai oyo ogotooretie aye omoruoti , nao rore ang’e nenyomba ya Hamani. Agwo omoruoti agachika “Gachie motonge Hamani ase orobambo roria igoro”

Naki amang’ana agendererete kobao ase egetabu eke gia Esteri nayekeene, naki ayio naro aragenderere kobao ekiagera naro oka akororekana ase amaiso aito akemwanyabanto, korende naboigo ayande nareo akororekana ase amaiso aito akemoika, ayio abisekanete korwa ase amaiso aito akemwanyabanto.

Naki ayio naro akogera ebinto bibere bigendererete gokorekana ime ase egetabu gia’Esteri, naki ime abwo amarube abere nareo aya Haribona’ naboigo na amaborio abere a ‘Esteri, naboigo amarube abere naende korwa ase Moredekai. Naki ayio naro agerete getabu eke kegiakwanera igoro ya Omonene Nyasae, nebe omonene Nyasae re gokwana na koiraneria amaborio abo, naki abanto baria bare aare na Nyasae tebamanyetie amang’ana akoba ang’e ase bare, tebari nokomanya ng’a omonene ngokra are ebikone bire ang’e na ase bare.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , ,
Category : Ekegusii (Kisii) | Blog
18
Jan

nigeria1KI A FI EMI MI BUN MI

Esteri 7:3-4 “ nigba naa ni Esteri ayaba dahun wipe, bi mo ba ri ore ofe loju re oba, bi o ba si wu oba, mo bebe ki a fie mi mi bun mi nipa ebe mi, ati awon eniyan mi nipa ibere mi. Nitori a ti ta wa, emi ati awon eniyan mi, lati run wa, lati pa wa, ki a le parun. Sugbon bi o se pe, ati ta wa bi erukunrin, ati erubinrin, emi iba pa enu mi mo, bi o tile je pe ota naa ko le di ofo oba.”

Eko yin so nipa ebe iketa Esteri niwaju oba. Nibiyi, Esteri fi ara bale alaye gbogbo ohun ti o nilo patapata. O wi fun oba ki o fie mi ohun bunu ohun. Ari eleyo ninu ebe adura fun igbala re,ati awon eniyan re.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
4
Jan

nigeria1ORU TI OBA KOLE SUN
Esteri 6:1-3. “Li Orun naa Oba kole sun, o si pase pe, ki a mu iwe iranti, ani irohun awon ojo wa, a si ka won ni waju Oba. A si rip e, ati koo pe, mordekai ti so Bigtani, ati Teresi, awon iweefa Oba meji, oluso iloro, awon eniti nwa ona lati gbe owo le Ahaswerusi Oba. Oba si wi pe, iyin ati ola wo li a fi fun mordekai nitori eyi? Nigbana ni awon omo odo Oba tin se iranse fun un wipe, a ko se nkankan fun wa ese eko ti aka yin so nipa ere to wa ninu awon idahun adura wa, Esteri ati awon eniyan to nse ara juda, won ti ngbawe ati adura fun itusile lowo iparun ti awon ota won ngbero lati mu ba won. Botile jewipe, Esteri ti koko gba ibunkun kan nitori awe gbigba re. nigbati oba fi tayotayo gba wole si agbala afin. Koda, nigbati owa lalai gba ase.

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog
18
Dec

nigeria1Esteri 6:6-10 “Beeni Hamani si wole wa, oba si wi fun un pe, kini a o se fun okunrin naa eniti inu oba dun si lati bu ola fun? Nje Hamani ro ninu okan ara re pe, Tani inu oba le dun si lati buola fun ju emi ti kalami lo? Hamani si da oba lohun pe, okunrin naa eniti inu oba dun si lati buola fun, je ki amu aso oba ti oba ima wo, ati esin ti oba ima gun, ati ade ti oba ti ima gbe ka ori re wa ki a si fi ewu ati esin yi le owo okan ninu awon ijoye oba ti o lola julo, ki nwon fi se oso fun okunrin naa, eniti inu oba dun si lati buola fun, ki o si mu un gesin la igboro ilu, ki o si ma kigbe niwaju re pe, bayi li a o se fun okunrin naa, eniti inu oba dun si lati buola fun. Nigba naa ni oba wi fun Hamani pe, yara kankan, mu ewu ati esin naa, bi iwo ti wi, ki o sise bee gege fun Mordekai, ara juda ni, ti njoko li enu ona ile oba, ohunkokhun ko gbodo ye ninu ohun ti iwo ti so”

continue

Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba | Blog