
Esteri 8:11 – “ Ninu eyiti Oba fi ase fun gbogbo awon ju, ti o wa ni ilu gbogbo, lati ko ara won jo, ati duro gba emi ara won la, lati parun, lati pa, ati lati mu ki gbogbo agbara awon eniyan, ati igberiko naa, ti o ba fe kolu won, pelu awon omo wewe ati awon obinrin ki o segbe, kin won ki o si ko ini won fun ara won”
Ara awon ohun to wuni lori ninu ninu iwe Esteri ni wipe, nigbati Oba se akiyesi idite lati pa awon eniyan ju run. (Gege bi Hamani se npete lati pa awon eniyan Olorun run patapata. Bakanna, ko si ona Kankan ti won le fi pagidina lasigbo yi ju ki Mordekai ati Esteri ro Oba lati fi ase fun awon eniyan Olorun lori awon ota won. Eleyi fi ara pe awon ofin Persiani igbaani. Eleyi ti won ma nyi ase pada, nipa sise a tunse, tabi ki won fagi le, Dipo eyi ti won o fi so di ewo fun enikeni lati gbogun ti awon omo ju, ofin titun fi ase fun gbogbo awon ju lati ko ara won jo, ati lati gba emi ara won la, lati parun, lati pa, ati lati mu ki gbogbo agbara awon eniyan ati ti igberiko naa, ti o ba fe kolu won.
Ni ona miran, eleyi nse apejuwe asotele ohun ti Olorun yio se nipase ijo olododo. Nigbati Jesu wa saye, o bori awon ota, nipase kiku lori igi agbelebu ati ni jijinde pada, gege bi Hamani se gba ere itiju ninu iwe Esteri. Bakanna, Jesu ko so wipe ki gbogbo emi esu ma farahan, ko ni ki inunibini ma farahan sori awon ijo olododo fun bi ogorun odun, gege bi oba se se ninu iwe Esteri, eleyi to fi fi aye gba idite lati fa awon eniyan olorun le hamani lowo.
Jesu fi aye gba awon agbara emi esu ninu aye yi fun awon asiko die. (wo johannu Kinin, 5vs19), Sugbon ogbe ijo olododo kale lati gberu ati lati gbile.
Eleyi soro fun opolopo eniyan lati gba gbo, ati, wipe, itan Esteri fun wa ni imole ati apere ti o ye koro, Jesu ti fun wa ni ase lati ko ara wa jo ati lati gba emi ara wa la nipase ti emi. (mo wipe, eleyi ko ni nkankan se pelu opolopo kristiani ti won nse janluku lode oni, eleyi ti ko sib a Bibeli mu)
“Nitoripe, ki ise eje ati eran ara li a wa mba jijakadi, sugbon awon ijoye, awon olola, awon alase ibi okunkun aye yi, ati awon emi buburu ni oju orun” (Efesu 6:12) A o gbodo wuwa janluku tabi gbogun ti elomiran nitoripe a un nse ise Oluwa.
O ye ki a ma ja ija ti emi, ki a si dabobo ijo olododo ninu eto Olorun.
LATI KO ARA WON JO: Fun wa, kiko ara wa jo, ninu Ore-Ofe ti Olorun. Fifun wa, lati duro gege bi ara Kristi fun ijo olododo. Ojuse akoko niwipe, lati dabobo ara wa ninu emi. Bakanna, nje emo wipe, idabo wa ninu emi, eleyi ti o le gbani sile, nigba ti a ba ni ibasepo ti o danmoran pelu awon onigbagbo totoo miran, nigbati a ba ko ara wa jo po lati dapo mo ise isin mimo lode omi, a ko ara wa jo po ninu ara ti Kristi, eleyi ti ijo si je ara ti awon onigbagbo, eleyi ti won ko ara won jopo lati ni ibasepo ninu adura gbigbaa. Eleyi ti isegun nla ti yio ti ibe jade wa.
Ase lati ko ra eni jo:= Olorun fun wa ni anfani ati oore ofe lati yan eyiti o ba wu wa. Ti a ba fe ko pa ninu ohun ti olorun nse ninu aye agbodo gbiyanju ki a tan ihinrerekale, a wa naa yio le kopa ninu ijo olododo, kkikuna lati seeyi, ko ni ki a ma lo si orun tabi pe ati dese. “ki a ma maa ko ipejopo ara wa sile, gege bi asa awon elomiran, sugbon ki a maa gba ara eni niyanju, pelupelu bi enyin tiri pe ojo ni nsunmo etile” (Heberu 10:25) lati parun, lati pa, lati ki o segbe. Ilekun ijoba orun apadi ko le bori ijo olododo*matteu 16:18).
Eleyi ko si ninu erongba olorun lati da oni jagidi-jagan, eniti nja ija esin lare, sugbon o san fun lati lo ona ore ofe fun itesiwaju si ijoba olorun, ati ki a si dabobo ijo olododo ninu eto olorun jade.
Kiko ini fun Ara won: won ko ko ara won jo nipase ase ara won (Esteri 9:9, Esteri 9:15) won ko si nipa ti ohun fe aye yi, sugbon lati gba awon eniyan olorun la. Agbodo ni imo eleyi gege be kristiani, idi ti olorun fi ngba owo wa se opolopo ise iyanu ati iasegub, ki ise lati so wa di oloro, sugbon fun eto ise igbala re, , eleyi tin se ti ayeraye lati mu wa tesiwaju.
Ti o ba fe kolu won: ko si tabi sugbon, ikolu ti emi ati ilakaka ninu aye yi yio sele, sugbon fun asiko tie ni. Olorun ti pese isegun sile, tio si ti pese gbogbo ohun elo ti anilo lati le bori gege bi asegun.
Translated from The Right To Assemble and Protect Themselves – Esther 8:11