Maranatha Global

The Spirit and the bride say, “Come!” – Rev. 22:17


6
Feb

nigeria1Esteri 8:8 “Enyin kowe ewe li oruko oba, nitori awon ju bi enyin ti fe, ki e si fi oruko oba ko, ti a ba si fi oruka oba se edidi, enikan ko le yi pada”.

Awon ijoba Persiani aye igbani, won ni awon asa ti ko ba ofin ijoba won mu.  Awon ofin ti awon alase ijoba gbekele ni o je wipe ko se yipada.  Eleyi ti o da opolopo wahala ati isoro sile ni gbogbo igba ti oba ba ti fe yi ase to ti pa lase pada.  Ko ni le tu edidi naa wo.  (wo Danieli 6:11-15, ninu itan miran, ti iru isoro bayi tun ti dide).  Ninu iwe Esteri, ona kan gbogi ti oba fi le yipada, ni ki oba fun igbakeji re lase lati yipada.

Awon ofin asa yi je nkan ajoji si wa laye ode oni, sugbon, niti Esteri, o se apejuwe re nipa ti eni igbala wa, si se a tun se pelu Olorun lati bo lowo idajo re labe ekunrere anu.

Awon ofin ododo Olorun je ayeraye eleyi ti a ko si le yipada “Looto ni mo sa wi fun yin, titi orun oun aye yio fi koja lo, ohun kikini kan ninu ofin ki yio koja, bi o ti wu ki ori, titi gbogbo re yio fi se” (wo matteu 5:8) tun wo Orin Dafidi 119:160, “ Otito ni ipilese oro re, ati olukuluku idajo ododo re duro lailai”.  Bi awa ko ba gbagbo, oun duro li olooto, nitori oun ko le se ara re.  (II Timoteu 2:13).  Gbogbo eniyan li o sa ti se, tin won si kuna ogo Olorun.  (Romu 3:23, Romu 6:23)

Bakanna, Olorun fe gbawala ninu ife re, ki o tun fun wa ni ile ayeraye.  (Johanu 3:16) koda, ko le ye majemu ofin re, tabi ki o gbagbe re, nitori pe, o duro titi lae.  (gege bi a se yannana re ninu ese to wa loke) otito si je ohun ise wa lati oke.  yiyan igbala lati koju si Olorun je isoro ti oba Ahaswarusi koju ninu iwe Esteri, eleyi ti o si je wipe labe ofin ko si eniti o le yipada, eleyi ti a si da gbogbo eniyan lebi iku.

Olorun si yanju gbogbo isoro yi fun wa pelu bi o se so ara re di eniyan (eyi ti a mo si Jesu) ti osi ku fun awon ese wa gbogbo.  jesu mu ofin naa se (Matteu 5 :17), o sit un gbe ofin titun miran kale.  Eleyi ti o fi otito oun tikarare han larin wa.  (Galatia 2 :16-21).  “Kristi ti ra wapada kuro lowo egun ofin, eniti a fi se egun fun wa, nitori ti a ti koo pe, ifibu li olukuluku eniti a fi ko sori igi”.  (3:13)

Ofin : ojulowo ofin ti a gbe le wa lori nigbati Adamu ati Efa kuna ninu ogba Edeni ni iku ayeraye.  “Gbo eniyan li o sa ti se, tin won si kuna ogo Olorun, ti won ko si ye fun iye ayeraye.  ”  (Romu 3:23, tun wo Romu 1:32).

Bakanna, “ki isi se bi nipa enikan ti o se die bun naa, nitori idajo ti ipase enikan waa fun idalebi, sugbon ebun ofe ti inu ese pupo wa fun idalare wa”.  (Romu 5:16).

Olorun wa, eleyi tin se oba awon oba, ti pese ona abayo fun wa, ni gbigbe ofin miran kale, eleyi ti aun peni igbala nipase eje (ti emimimo) ti Jesu Kristi.  eleyi ti ati so asotele re ninu iwe Jeemaiah 31:31-33.  “woo, ojo nbo, li Oluwa wi, ti emi o ba ile Israeli ati ile Juda da majemu titun, ki ise bi majemu naa tie mi ba baba won da li ojo naa tie mi fa won lowo lati mu won jade lati ile Egipti awon ti nwon da majemu mi, bi emi tile je alakoso won si be li oluwa wi, sugbon eyi ni majemu tie mi o ba ile Isaeli da, lehin ojo wonni, li Oluwa wi, emi ofi ofin mi si inu won, emi o si ko o si aya won, emi o si je Olorun won, awon o si je eniyan mi koda iw majemu titun se alaye re yekeyeke “o si ti pa iwe maemu ni re, ti o lodi si wa, tia ko ninu ofin, eyiti o lodi si wa, oun li o si ti mu kuro loju ona, o si kan an mo agbelebu” (Kolose 2:14) “Sugbon ni sinsinyi a fi wa sile kuro ninu ofin, nitori a ti ku si eyiti a ti de wa sinu re, ki awa ki o le maa sin li otun emi, ki o ma se ni ode ara ti atijo” (Romu 7:6).  Ko le yii pada, ko tun si ona abayo kuro ninu ofin iku yi, bi kose lehin eje Jesu Kristi.  Igbala ko wa lati odo eniyan, bi kose lati odo Olorun.

Oruka oba: oruka yi duro gege bi majemu, lode oni, a ni majemu titun nipase emimimo, eleyi to fun wa ni agbara nigbogbo igba si ori ite Olorun wa.  (wo II Korinti 1:22, Efesu 1:13, Efesu 4:30).

Awon ju : nitori pe gbogbo eniyan ni yio koju idajo, kii se fun awon die (wo Johanu 3:16, II Peteru 3:9).

Fifi Oruka O ba Se Edidi Re was translated from Esther 8:8 – No Document Can be Revoked

Have questions or interested in more information on this topic? Please ask a pastor.
Tags : , , , , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba