1 Korinti 13:4 “ife a ma mu suru, Ife a ma seun, ki se ilara, Ife ki se igberaga, Ife ki se ohun aito”.
(translated from the English lesson Love Does Not Envy)
Ife ki fe ohun ara re nikan, o dunu si aseyori ati aluyo elomiran, ilara nse idakeji eyii. Ife kristieni ma n fe fi ogo olorun han ninu aye elomiran ife ti ase apejuwe re ninu 1Korinti 13, ko je imolara tabi isise. Ni ti giriki (greek) lo ni ona ti o yato nibi ju. Oro fun emi isise tabi topolo, ife ti an soro nipa re nibi je ti oun ti a yan, ifihan ise ti eyi ti a fi suru gbin ninu ara wa. Iru ife yi ki se ilara. Ilara ati ife ko bara dogba, Ilara a ma pa ise Olorun run. Koda, aidara yi waye pelu isubu ninu ese pelu awon Kristieni, Awon ti won sun mo olorun pekipeki ti won sise to lagbara fun. Eran ara ro pe ilara ti wa be ko si le se yago fun, sugbon ko ye w ape,ko si awawi fun. Bibeli ki lo fun wa lori ilara ati owu (Romu 13:13, 1 korinti 3:3, 2 korinti 12:20, Galatia 5:20:26, 1Timoteu 6:4, Titu3:3, jakobu 3:14 – 16, 1peter 2:1)
Bawo lase le tumo ilara? Ilara se ifaseyin elomiran nigbati won ba ni nkan ti a ko ni, bi aseyori won, tabi ise re, tabi Aluyo ti won ri gba, ti a wa nwa isubu, ikosile, ati awawi si ru eni be bi otile je wipe ko se ohun ti olodi.
Idojuko opolopo awon ise ninu bibeli da lori ilara latodo awon igun keji won, koda ninu akori iwasu ni asiko ijosin, ti oni wsasu feran lati ma naa ka alebu tabi ki o ma mu enu baa won iwakiwa ti awon eniyan kan tiwu. Iru ese yii yio kan ma pa eniyan ti o se lara ni. Ilara tabi owu jije ma n pa ni lara ninu ijo. Nitori na o tun nse ipalara fun ara Kristi nigbati aba nwa anfani lati odo awon ti won n gbe – ninu ese.
Awon Arakorin Josefu korira re, won si tani eru, Nitori ilara ati owu jije (Genesisi 37) kora gbe awon iko olete dide si mose nitori iwa ilara (Numeri 16) Penina npon Hanna loju nipase owu jije(1samueli1)Saulu gbiyanju lati pa Dafidi lopolopo igba nipase owu jije(1samueli18-20)Ilara gan ni idi Pataki gan ti awon farisi ati sadusi fi fi jesu oluwa wa le iku lowo (matteu 27:18,marku 15:10) yiyipada paulu kuro ninu eran ara,eleyi gan lo mu ogun aifokanbale ati ainidunnu wa fun lati odo awon oni lara olusoagutan ninu ijo akoko(2 kor.10:12)ni ona miran,ilara duro gege bi ese apanirun kansoso lati pa awon iranse olorun toto lara.Fun apeere, boya oje diakoni ninu ijo,boya diakoni miran tun ni agbara ba se le waasu ati bi a sele dari, tabi ko ti han si gbangba pe oun ni opon sun kan lati ta ororo si lori gege bi oluso agutan. Je ki nbi o lere,se wa feran re ni tabi se wa se atileyin fun, Abi wa tori ife tara re korira arakunrin naa?abi oti ri awon alebu ninu awon iwaasu toti seri,?je ki ntun so fun o ife ki se ilara.Fun apeere miran,boya o je odomobinrin ti o ni oju se Pataki ninu ijo,se o wa ma tako arabinrin ti oje wipe gbogbo eniyan n woo,to tun je wipe oni awon ojuse to ju tire lo ninu ijo tabi eyiti oko re ngba owo to gbe peli ju tire lo?.Se gbogbo oro asotele ati ti ifihan to mu wa loje ibi lori awon arabinrin naa?.Ife ki se ilara.Nigba miran, boya iranse tabi oluso agutan kan ripe oluso agutan miran tun ni orisirisi ebun to ju ti ohun lo tabi ori pe awon araye n gba ti e ju ti ohun lo, ife Kristi gbodo mu inu re dun si arakunrin re.won tun gbodo ma le pa bi yio se se aseyori ninu ise iranse re siwaju ati siwaju si.Eleyi ni yio je ohun ti o dara julo,pe a jere ohun to dara ninu ise olorun,sugbon elomiran nma wa afanni lati le ma gbeni lese ati ki won tun le ba ni wi,won a tun ma so oro aida nipa re nigba ti ko ba si nibe tabi ti ko pari awon ojuse re daradara.Awon miran nma fi ipo Pataki won fi yepere ojuse awon miran. atunbotan eleyi si ma nje ki awon okunrin yoku rira won gege bi eniti ko ja mo ohun kankan. koda,won onile da nkankan se eleyi ti o je adanu fun ise olorun.ife ki se ilara.Jesu fun wa ni apejuwe ti o yanranti lori “ife”gege bi ase se apejuwe re ninu iwe 1korinti 13.Jesu ni suuru,jesu si tun seun lopolopo.Jesu ki se ilara,ko da,ada jesu mo patapata gege bi omo ti baba fe,ti o si ngbe ninu ife fun gbogbo wa,ati fun awon alatako re.ilara ki se ohun ti Kristi fe.agbodo yera fun eleyi gege bi ese ati idanwo.nitori pe ife fe ohun to dara fun omonikeji, osi tun gbodo ma wa aseyori fun omonikeji ati lati le so eso ti emi.
IFE KI SE ILARA translated from Love Does Not Envy – 1 Corinthians 13:4
Translated By Omoniyi Johnson