Maranatha Global

The Spirit and the bride say, “Come!” – Rev. 22:17


9
Jul

nigeria11-150x1502Deuteronomi 30:19 – “Nisinyi, Yan iye, ki iwo ki o le ye, iwo ati iru omo re.”

Deuteronomi 30, o je ikan lara oro idagbere ti mose ba awon omo Isreali so. Gege bi woli olorun, omu awon oro to se Pataki wa fun awon eniyan na la koko naa. Awon omo Isreali kun fun aroye sise lakoko ti won fi wa ninu aginju. Ni akoko na, won ti gbaradi patapata lati wo ile ileri. Opolopo awon ti won jo fi ile Egypiti sile ni won ti ku, won ku sinu aginju nitori aigboran won. Iran tuntun miran si dide, Awon ti won wa ni omode ni akoko ti won fifi ile na sile.

Irekoja mose ati iran re oje ipa elo fun wa ni akoko yi. Bakanna ari ipa ohun emi to se Pataki, bi ti isiloju ti otun fun erongba ti olorun. Olorun fun eniyan lagbara lati yan eyiti obawu.(yiyan iye ). Oro yi waye ni ipari asiko ti olorun se awon ise ami ati iyanu nla, sugbon awon eniyan wonyi ko ni oye ise ami wonyi. Asiko yi tun je asiko igbekale igba otun ti ale bori awon orisirisi isoro lati le jogun ile ileri naa. Ni ona miran ije olododo ati igboran nran ise iyanu lowo ninu aye eniyan.

Asiko ti o ti rakoja lo yi je asiko ti olorun ran awon iyonu mewa si ori ile egypiti. Opin okun pupa niya, o si nko awon eniyan re sodi nipase owon ina ni asale ati awo sanmo ni osan, osi pese ounje fun won ni ona iyanu. (mannaa ati aparo) osi mu omi jade wa lati inu apata, o si daso ro won eleyi ti ko si gbo. Eyi ni iyanu gbogi ti owo ja re si tan ka gbogbo orile-ede agbaye, eleyi si fi titobi olorun han. Ni ona miran, awon eniyan wonyi funra won mo igba ti nkan bansedede fun won, Nigba na won a tele olorun, sugbon ti nkan ba ku die kato won o bere si ni ma se awawi ati siso oro odi si olorun. Won jade kuro ninu ipo eru wa ni Egypiti, gbogbo opolo ori won kun fun ti eru, ko da won o le da ipinnu ara won se lati yan eyiti oto ati lati da awon ise ti emi mo gege bi asiko yi se pari, olorun pan ni dandan fun wa lati yan iye.

Awon oluko iwe majemu titun papa ri wipe Asiko yi je Asiko to kun fun ise ami ati iyanilenu sugbon gbogbo awon eniyan naa parun patapata (wo 1Korint. 10:10 – 12, Juda 1:15) eleyi je aditu, Ni ona ti opolopo awon ise iyanu ti o gajulo n fi sele pelu eniyan ti won ko le duro de ife olorun tabi awon to je wipe ko sese fun lati de ibi Ayo won. Iwasu lori yiyan iye dalori igbe aye otun ti o se Apejuwe ise agba iyanu ju awon isegun ti eniyan nri gba nipa gbigboran si olorun ati lati wo inu ile to n san fun wara ati fun oyin. Awon iyanu ko kara ti n fara han. Bi ti wi wolule odi Jeriko tabi bi orun se duro pa si oju kan lati mo eni ti yio bori ninu iwaya – ijab (wo Joshua 10). Ni gbogbo igba awon ise ami yi nduro gege bi olorun lati to won sona bi won sele ko ju awon ogun ati lati bukun won fun aseyori won to yanilenu gege bi won se fi ise re han si ita. Gbogbo awon ti won gbo ti won si di ofin re mu sinsin ni won yan iye, ni won si tun wo ileri pelu Joshua. Igba otun yi n se apejuwe awon igbese ati ti ilakaka to la gbara to fun won ni aseyori. Awon eniyan wonyi ti yan eyiti o wu won. Olorun ti se eyi, sugbon nisinyi ohun nsise nipase awon eniyan re, Teleri, olorun nma duro fun won, Koda lari rin won.

Ni aye odeoni, “Yiyan – IYE je oro ti a mba wa so, awa ni eniyan re, o je akoko to se pataki, akoko isotele, asiko igbeyin yi n se apejuwe ise ami ati ise iyanu eyiti oya awon kristiani agbaye lenu. Imubosipo awon ebun emi, iwosan, asotele, ati ti ise iranse onidipo marun (Efesu 4:17), ati bebe lo, pee awon ise ami yi ri bakanna pelu awon eyiti afilele ninu ise awon apostoli. Bayi olorun ti fun wa ni anfani lati yan eyi to ba wuwa. Nitorina awon igbese ta ni la ti gbe gbodo je eyi ti yio gbe wa wo inu eto ile ayeraye to ni fun wa lo. Igba atijo yi fi opolopo ise iyanu nla han, Sugbon opolopo kristiani na ni won mo riri awon ise iyanu ti won ri gba naa. Olorun mu opolopo eniyan kuro ninu asa ati esin to ti ku to ti run, sugbon sibesibe awon eniyan miran ko ti gba eto olorun fun ayeraye.

Ko da awon ojo to si wa niwaju se Pataki pupo, Ni igbaradi to gbeyin fun igbasoke awon ijo olorun, Wiwo inu ile ileri lo niise pelu ohun nla meji, kikore awon okan koto di wi pe o pe ju .( leyin igbasoke) ati pipari ise olorun larin awon ijo olododo ati awon ti ko ni abawon kankan. Gege bi Joshua pelu awon akegbe re . oju miran gbodo ni agbara lati le pari awon ise takunkun eleyi to gbodo jasi aseyori nla lati le gbe ohun ti olorun fe jade. Olorun nko awon eniyan jo ki ole sise larin won, ki kan se fun won lasan, ti a ba wo ogorun odun seyin ti olorun tun nfi ara re han awa kristiani loni pe ohun ti nse opolopo ise iyanu lode oni, o n fi yewa pe olorun tin se oniriru ise ninu agbara re.

Awon eniyan olorun si duro ni eti bebe ile ileri ti won si se tan lati wo ibe ati lati mu gbogbo ohun ti olorun fe se lati atetekose. Ni asiko yi, gege bi ase duro lati yan eyiti oba wuwa, o pe wanija pe ka yan iye. Awon eniyan ti won yan eyi pinnu lati gboran ati lati se ife re, won osi ye bakanna, won osi tun gba isegun.

YIYAN IYE

Translated by Omoniyi Johnson

+8062140757

Have questions or interested in more information on this topic? Please ask a pastor.
Tags : , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba