Maranatha Global

The Spirit and the bride say, “Come!” – Rev. 22:17


9
Jul

nigeria1Deuteronomi 2:7 - “Nitori ti olorun re ti bunkun o ninu ise owo re gbogbo, o si ti mo gbogbo irin re ninu aginju nla yii. Ni ogoji odun yii oluwa olorun re ti mbe pelu re; oda ohun kan ko da o”

IFAARA

A ngbe ninu ilana olorun fun ise yi, asiko to farape eyi to sele ninu itan awon omo Isreali gege bi ese bibeli ti a ka. Ti ipa asotele eyi ti o se Pataki fun wa lati mo ni ohun to sele pelu Isreali gege bi eyi to sele ninu aye awon ijo lode oni, nitori wipe won dogba pelu itan larin awon eniyan ati itan ti ijo.

1. OLUWA TI BUKUN O NINU GBOGBO ISE OWO RE.

Owo olorun tin wa larowo to lati fidi ise owo re han larin awon eniyan.

- Nigba ti won nkuro ni Egypiti.

- Nigbati won la okun pupa koja.

- Lori oke Sinai- Nipa Iribomi ti emi- mimo.

- Bibori awon ota ni oju ona naa.

- Ti won koja lori odo jodani.

Ninu gbogbo akawe olorun ti wa pelu awon eniyan re, Lati bukun ise owo won.

2. O MO OHUN TI NWON LA KOJA NINU AGINJU NAA.

- Olorun mo awon isoro ti awon eniyan re doju ko ninu irin ajo ninu asale,ati iyangbe ile.

- Orun to tara- to gbona gidigidi losan ati otutu larin oru, tabi awon iji ninu asale.

- Loni awon ijo rin ninu aye ti o kun fun orisirisi idojuko, sugbon o mo pe ki se awon nikan.Fun olorun lati fetilele fun awon isise re olorun mo ibi ti a kusi ati bi a se mo, sugbon eyi ko di lowo lati ran wa lowo.

- Igba kan wa ti isreali gba idiwo (“ yi pada si gusu”), beni ijo se lati gbe igbe aye ti atijo ati lati bere irin ajo tuntun.

3. IWO KO PADANU OHUN KANKAN.

- Orun si wa sibe

- Be si ni ina ni oru.

- Eyi si ni ohun elo lati mu won tesiwaju, lati fi han awon eniyan wipe irin won ko le yinje nitori irin akoni ni won rin.

Beni si ni won ko se alaini

- Mannaa (jesu je akara ayeraye ). Awon ijo ni iriri, ti won fi gbe lati ojo de ojo, ni eyi ti won ti gba lati odo olorun wa gege bi mannaa ti olorun ran si awon eniyan re ninu aginju. O so irin won ni owuro kutu, ki orun to yo, koto dipe won alakaka ni eyi to wopo ni owuro, awon ijo ti gba ipa ti ounje won fun irin ajo na. iri ase lewon lori gege bi itura ati pelu mannaa lati orun wa.

- Ti aparo (jesu je akara emi to wa latorun). Won so nipa jesu alaye to fi ara re han fun ijo.

- Nipa ti omi (jesu je omi emi) ti a da ibukun ti emi-mimo jade sori awon ijo lati pana orungbe ninu irin ajo won.

- Ohun ti ko je ki won padanu ninu kikoja tabi lila odo jodani koja to si kun akunwosile. Ako awon elo yi po fun awon eniyan naa.

- Ti won ba ti koja si odi keji won ti wa ni ti ona olorun emi- mimo patapata ati wipe, ti won ba ti gbe oro naa ga ohun to ku ni ki won wole si ile na.

Ni akotan

- Lode oni anjere ninu abajade iranlowo olorun eyiti o fi ranwa lowo nigba gbogbo fun ogoji odun ti ati wa ninu ise re, to si fun wa lagbara lati le koju awon ipenija to le suyo ni ojo iwaju, amope ni iwaju wa ni orisirisi ilakaka wa, isoro ati irobinuje, Sugbon ani idaniloju ninu olorun to wa pelu wa di oni yi wipe yio si tun ma tesiwaju lati wa pelu wa. Akoni salaini ohun to dara.

OGOJI ODUN NI AGINJU

Translated by Omoniyi Johnson in Nigeria, +8062140757
Have questions or interested in more information on this topic? Please ask a pastor.
Tags : , , , , , , , , , , ,
Category : Yoruba