One of the main Nigerian languages – spoken by approximately 28 million people. Also spoken in parts of Benin, Togo, and wherever large Nigerian immigrant populations are located.
Nje Aluyo Nipa Ti Ara Je Ami Wipe, Olorun Fi Owo Si Yiyan ?
Filippi 4:12 – “Mo mo bi aa ti ise dir ire sile, mo mo bi aa ti ise di pupo, li ohunkohun ati li ohun gbogbo mo ti ko asiri ati maa je ajeyo ati lati wa li aije, lati maa ni aniju ati lati se alaini.”
Ileri Olorun Fun Dafidi
I Kronika 17:1-4 “O si se, bi Dafidi ti joko ninu ile re, ni Dafidi so fun Natani woli pe, emi n gbe inu ile Kedari, sugbon apoti eri majemu Oluwa ngbe abe aso tita. Nigba naa ni Natani wi fun Dafidi pe, se ohun gbogbo ti m be ninu re, nitori ti Olorun wa pelu re, o si se ni oru kan naa ni oro Olorun to Natani wa wipe, lo, si so fun Dafidi iranse mipe, bayi li Oluwa wi, iwo ko gbodo ko ile fun mi lati ma gbe”
“La Mi Li Oju, Ki Emi Le Ma Wo Ohun Iyanu Wonni Lati Inu Ofin Re”
Orin Dafidi 119:17-19
“Fi opolopo ba iranse re se,ki emi ki o le wa laaye, ki emi kio le pa oro re mo. Lami li oju, ki emi ki o le ma wo ohun iyanu wonni lati inu ofin re. Alejo li mi li aye, maase pa ase re mo fun mi.”
Orin-Dafidi 119:1-8
Ibukun ni fun awon eniti o pe li ona naa, ti nrin ninu ofin Oluwa. Ibukun ni fun awon tin pa eri re mo, ti si nwaa kiri tinu-tinu. Nwon ko dese pelu, nwon nrin li ona re. Iwo ti pase fun wa lati pa eko re mo gidigidi, ona mi iba je la sile lati ma pa ilana re mo. Nigba naa li oju ki yio ti mi, nigbati emi ban juba ase re gbogbo, Emi o ma fi aya diduro sinsin yin o, Nigbati emi ba ti ko idajo ododo re, emi o pa liana re mo, mase ko mi sile patapata.
OJUSE LATI LODI SI ORO EKE
Lefitiku 5:1. . “Bi enikan ba si se, ti o si gbo ohun ibura, ti o si se eleri, bi oun ba ri tabi bi oun ba mo ti ko ba wi, eje ki o ru aisedede re”
Bibeli ko w ape ani ojuse lati se ati lati se awon ohun ti otoo. Ninu opolopo igbese wa, eleyi ti o je wipe, awon ohun ti a ro pe, a ko se le je ese to buru pupo. “ Nitori naa enit ti o ba mo rere ise ti ko si se, ese ni fun-un” (Jakobu 4:17) opolopo ilana ofin kakiri orilede agbaye, niwon ko bojuwo esun aileso ohun ti otoo. Olorun nreti awon ohun kan lati odo wa pe, ki a ma se ati wipe ki a ma se awon nkan aigboran. Ese iwe ti a ka ninu iwe lefitiku yi, fun wa ni apeere eyo kan. O fun wa ni eko ti ose Pataki, eleyi ti o le ran awon ijo abele lowo lati ni okun ife ti o danmoran ati ifowosowopo ti o tobi lati le jo sise papo gege bi iko. Olorun fe ki a se atunse lori gbogbo oro eke, eleyi ti a se lodo si eniyan miran nigbati a gbo won. Eleyi ko so fun wa wipe, ki a so ara wa di wolewode tabi ki a ma se ayojuran si ibi ise tabi okowo elomiran.
1Korinti 13:6 “Ki iyo si aisododo, sugbon a maa yo ninu otito”.
Ife Amaa yo Ninu Otito
Eleyi le je ohun ti o faa, ti a ko fi menu ba awon oro kookan ninu iwe 1korinti 13. Nigbati awon eniyan mba nro nipa oju ewe ife ti o tobi ju ninu iwe paulu. Nigbogbo igba ni nwon maa nro wipe, boya nipa oyaya, tabi ki iwa eniyan dara, ati bi iru awon ohun ti amu enu baa ninu iwe 1korinti 13-4-5. Oje ohun ti o sowon ka to le gbo iwaasu lori “ife” ni ona ti o je wipe, amaa yo ninu otito, tabi, ki iyo si aisododo. Bakanaa, Ese yi fi ipa gbogi iyipada han ninu eko lori ife. Ninu gbogbo eso ife ti a ka sile, (Eso kesan wa ninu iwe 1korinti 13-4-5), Eleyi ti oni ise pelu ibasepo wa ati bi aun nse se pelu awon eniyan wa ninu ile ijosin. Nibiyi, aun ri eso iwa olukuluku, eleyi to nfi itara ife atokan wa onikuluku han, eleyi ti ki ise wipe ki won kan saa ti mon wipe ani ibasepo pelu awon eniyan eleyi ti o yi wa ka.
IFE KI NI AKOSILE ASISE
IKorinti 13:5 “Ki ihuwa aito ki iwa ohun ara re, aki imu un binu beeni ki igbiro ohun buburu.” Idi niyi ti bibelim (KJV).
Ninu oro ti paulu so yii, tumo si pe lati ma ro oun buburu, tabi lati ma ko awon akosile asise ati iwa buburu. “Idi niyi ti bibeli (KJV) tun fi se alaye ju awon eya bibeli titun ayeode oni lo. Bakanna, eniyan to un gbe ninu ife, ko nilo lati ma ko asise ti omonikeji ba se si ninu ijo, ka si ma ma fi gbogbo igba foju si awon ohun buburu ti a se si wa, eleyi to le ma mu wa, wa ona lati gbesan. Ninu awon ise ife ati iwa ife, toun nfi ihuwa si wa han si elomiran.
Bibi Olorun Lere Nipa bi ase le Gboran Si Ife Re
Onidajo 1:1-2. “O si se lehin iku josua, ni awon omo Israeli bere lodo Oluwa wipe, tani yio tete goke to awon ara kenaani lo fun wa, lati ba won ja? Oluwa si wipe, juda ni yio goke lo. Kiyesi emi fi ile na lee lowo.
Ese Rehoboamu
1Awon Oba 12:12-15. “Beeni jeroboamu ati gbogbo awon eniyan naa wa sodo Rehoboamu ni ijo keta, geg bi oba ti da wipe, e pada to mi wa ni ijo keta, oba si da awon eniyan li ohun ako, O si ko imoran awon agbagba ti nwon baa da. O si so fun won gege bi imoran awon ipere wipe, Baba mi mu ki ajaga nyin ki o wuwo, emi o si bu kun ajaga nyin, baba mi fi pasan na nyin, sugbon akeeke li emi ofi na nyin. Oba ko si fi eti si ti awon eniyan naa, Nitori ti oran naa ati owo Oluwa wa ni, ki ole mu oro re se, ti Oluwa ti owo Ahijah, ara silo so fun jeroboamu, Omo Nebati.”
Reheboamu gbe igbese eleyi to mu ki isokan Orilede awon omo Israeli, eyiti o ti wa bi aimoye ogorun-odun sehin pinya. Lori igbese yi, omu ki Olorun yan awon orilede ti a pinya si ekun ijoba ariwa, eleyi ti aun pe ni “Samaria” tabi”Israeli”, ati ekun ijoba gusu, eleyi ti aun pe ni judia. Eleyi to wa ninu awon eya juda, Benjamin, lefi, ati Simoni. Olorun ti so asotele nipa isele yi ni opolopo odun sehin nipase woli re. Eleyi wa je ijiya si aigboran awon olori ati awon eniyan lasiko ijoba solomoni. Ara koko kan ti eko yi nko wa ni wipe, awon ese wa, ati asi se wa ni kan ko loun nmu idajo wa, Sugbon awon naa wa lara oun to un mu idajo Olorun wa, awon bi iwa aigboran, ti a ti wu sehin. Eleyi je ise ninu gbogbo bibeli. (Wo Orindafidi 18:12, Ezekieli 20:25, Ise Awon Apostoli 7:42, Romu 1:24-28, II Tessalonika 2:10-11) Ninu awon ise kokan bayi, nigbati eniyan fi ara re sinu ipo ife ara re, ti o si feran lati ma se aigboran si Olorun, Sugbon die lara idajo ese re ni wipe, o gbe awon igbese ti ko dara, eleyi ti o wa dakun ese re.
Aso Titun WaSekariah 3:1-7, “O si fi josua olori alufa han mi, o duro niwaju angeli Oluwa, satani si duro lowo otun re lati koju ija sii. Oluwa si wi fun satani pe, Oluwa ba o wi, iwo satani, ani oluwa ti oti yan jerusalemu, oba o wi, igi ina ko eyi ti a mu kuro ninu ina? A si wo josua li aso eeri, osi duro niwaju angeli naa. O si dahun, o wi fun awon ti o duro niwaju re pe, Bo aso eeri ni kuro li ara re. O si wi fun un, pe, woo, mo mu ki aisedede re kuro lodo re, emi osi woo li aso eye. Mo si wipe, je ki won fi lawani mimo wee li ori. Nwon si fi lawani mimo wee lori, nwon si fi aso woo. Angeli Oluwa si duro tii. Angeli Oluwa si tenu mo fun josua pe, Bayi ni Oluwa awon omo ogun wi, bi iwo o ba rin li ona mi, bi iwo oba si pa ase mi mo, iwo osi se idajo ile mi pelu, iwo osi pa aafin mi mo pelu, emi o si fun li aye ati rin laarin awon ti o duro yi. (Sekariah 3:3-7).