One of the main Nigerian languages – spoken by approximately 28 million people. Also spoken in parts of Benin, Togo, and wherever large Nigerian immigrant populations are located.
Siso Ilodi Si Olorun
Malaki 3:14-17 “Eniyan ti wipe asan ni lati sin Olorun, anfani kini o si wa, ti awa ti pa ilana re mo, ti awa si ti nrin ni igbaawe niwaju Oluwa awon omo Ogun?. Sugbon nisinsinyi, awa pe agberaga li alabukun- fun, looto ti o nhuwa buburu npo sii, looto awon ti o dan Olorun wo li a da sii. Nigba naa li awon ti o beru Oluwa mba ara won soro nigbakugba, Oluwa si teti sii. O si gbo, a si ko Iwe-iranti kan niwaju re fun awon ti o beru Oluwa, ti won si nse asaro Oruko re. Nwon o si je temi ni ini kan, li Oluwa awon omo ogun wii, li ojo naa ti emi o da won sii gege bii eniyan tii ma nda omo re sii, ti o nsin-in”.
Awon Ojuse Diakoni
1 Timoteu 3:8-13 “Bee gege li o ye fun awon diakoni lati ni iwa agba, Ki nwon ma je elenu meji, ki nwon ma fi ara won fun waini pupo, ki nwon ma je olojukokoro, ki nwon maa di ohun ijinle igbagbo mu li okan funfun, ki a si ko wa idi awon wonyi daju pelu, nigba naa ni ki a je ki nwon je oye diakoni, bi nwon ba je alailegan. Bee gege li o ye fun awon obinrin lati ni iwa agba, Ki nwon ma je asoro eni-lehin bikose alairekoja, olooto li ohun gbogbo, ki awon diakoni je oko obinrin kan, Ki nwon ki o kawo awon omo won ati ile ara won daradara, Nitori awon ti o lo oye diakoni daradara ra ipo rere fun ara won, ati igboya pupo ni igbagbo ti mbe ninu Kristi Jesu. “
Jesu je Opagun Fun Awon Eniyan
Isaiah 11:6-11 “Ikooko pelu yio ma ba odo-aguntan gbe po, kiniun yio si dubule pelu omo ewure, ati omo malu ati omo kiniun ati egboro eran abopa yio ma gbe po, omo kekere yio si ma won. Malu ati beari yio si ma je po, omo won yio dubule po, Kiniun yio si je koriko bi malu. Omo enu omu yio si sire ni iho paamole, ati omo ti a ja lenu omu yio si fi owo re si iho gunte. Nwon ki yio panilara, beeni nwon ki yio panirun ni gbogbo oke mimo mi, nitori aye yio kun fun imo Oluwa gege bi omi ti bo okun. Ati li ojonaa kukute Jese kan yio wa,ti yio duro fun opagun awon eniyan, Oun li awon keferi yio wa ri, Idinmi re yio si li ogo. Yio si se li ojo naa,ni Oluwa yio tun nawo re lati gba awon eniyan re iyoku pada, ti yio ku,lati Assiria, ati lati Egipti,ati lati Patrosi, ati lati kusi, ati lati Elamu, ati Sinari, ati lati Hamati, ati lati awon erekusu okun wa.”
Awon Emi Meje Olorun
Isaiah 11:1-3. “Eekan kan yio si jade lati inu kukute jesse wa, eka kan yio si hu jade lati inu gbongbo re. Emi Oluwa yio si ba lee, emi ogbon ati oye, emi igbimo ati agbara, emi imoran ati iberu Oluwa, Oorun didun re si wa ni iberu Oluwa, oun ki yio si dajo nipa iri oju re, beeni ki yio dajo nipa gbigbo eti re.â€
Awon Ifihan Onikaluku ati Oro re
Orin Dafidi 119:133- “ Fi isise mi mule ninu oro re, ki o ma si je ki esekese ki o joba lori miâ€
Gege bi Kristieni, aun ngba ifihan Olorun ni ona meji. Nipase Bibeli ati Emimimo, eleyi to un ngbe ifihan jade. Eya ifihan meji yi, nti ara won lehin, ati wipe gege bi Bibeli nse ntenumo, to un si ko w ape, Olorun yio ba wa soro, ati wipe, yio sit un dari wa ninu emi ati wipe, emi yio si ma ti wa loponpon lati mu wa jinle ninu emi ati ninu oro Olorun.
OLORI FUN IJO
KOLOSSE 1:18 – “Oun si je ori fun ara, eyini  ni ijo, eniti ise ipilese, akobi lati inu oku wa, pe ninu ohun gbogbo ki oun ki o le ni ipo ti oga julo.â€
Kini awon ohun ti omu iyato wa sinu awon ojulowo ise Olorun ninu ohun gbogbo eleyi ti aun n ri ni awon ayika wa? Ni ona gbogi, pipe eje Jesu ti mu ki a se awari awon nkan meta. Wiwasu ifihan oro, titele ilana ati idari ti emimimo, dipo awon ero ati ki opolo ti eniyan nro, ati ki ani ibasepo pelu Kristi.
Nje Aluyo Nipa Ti Ara Je Ami Wipe, Â Olorun Fi Owo Si Yiyan ?
Filippi 4:12 – “Mo mo bi aa ti ise dir ire sile, mo mo bi aa ti ise di pupo, li ohunkohun ati li ohun gbogbo mo ti ko asiri ati maa je ajeyo ati lati wa li aije, lati maa ni aniju ati lati se alaini.â€
Ileri Olorun Fun Dafidi
I Kronika 17:1-4 “O si se, bi Dafidi ti joko ninu ile re, ni Dafidi so fun Natani woli pe, emi n gbe inu ile Kedari, sugbon apoti eri majemu Oluwa ngbe abe aso tita. Nigba naa ni Natani wi fun Dafidi pe, se ohun gbogbo ti m be ninu re, nitori ti Olorun wa pelu re, o si se ni oru kan naa ni oro Olorun to Natani wa wipe, lo, si so fun Dafidi iranse mipe, bayi li Oluwa wi, iwo ko gbodo ko ile fun mi lati ma gbeâ€
“La Mi Li Oju, Ki Emi Le Ma Wo Ohun Iyanu Wonni Lati Inu Ofin Reâ€
Orin Dafidi 119:17-19
“Fi opolopo ba iranse re se,ki emi ki o le wa laaye, ki emi kio le pa oro re mo. Lami li oju, ki emi ki o le ma wo ohun iyanu wonni lati inu ofin re. Alejo li mi li aye, maase pa ase re mo fun mi.â€
Orin-Dafidi 119:1-8
Ibukun ni fun awon eniti o pe li ona naa, ti nrin ninu ofin Oluwa. Ibukun ni fun awon tin pa eri re mo, ti si nwaa kiri tinu-tinu. Nwon ko dese pelu, nwon nrin li ona re. Iwo ti pase fun wa lati pa eko re mo gidigidi, ona mi iba je la sile lati ma pa ilana re mo. Nigba naa li oju ki yio ti mi, nigbati emi ban juba ase re gbogbo, Emi o ma fi aya diduro sinsin yin o, Nigbati emi ba ti ko idajo ododo re, emi o pa liana re mo, mase ko mi sile patapata.